Olodumare Lyrics by 9ice

9ice Lyrics
Read 9ice's Olodumare lyrics and feel the unique emotional weight of each line, from the poignant ballads to the uplifting anthems that resonate.

9ice - Olodumare Lyrics
Emi kan eda kan
Aye kan lo wa
Emi kan eda kan
Aye kan lo wa
Ah ah
Ti n ba n lo lona maa ko ire
Abo mi ma n da ore
Gbogbo irin ti mo ba n rin ma n d′oore
Gbogbo i e ti mo ba n se lo ma n d'ope
Ti n ba n bo ni ibikan
Ti n lo si ibikan
Maa gba ire
Ti mo ya si ibi kan ma gb′ope
Ona mi ma n fo ire
Olodumare lo je ko ri bee
E ni mo ya ma n dake s'ope
Olodumare olori
Olodumare adari
Olodumare mare
Olodumare mare
Sebi iwo ni adakeja bi idan
Ajabi-epe bi ara o
(Baba baba ah)
E mi lore a wow
Saanu omo o re
Baba mi
(Baba baba ah)
Ma dawo oore re duro
(Saanu omo o re)
Iya o le je mi tori mi o p'awo da
Okanlomo (Anaconda)
Colour media
(Cosatira)
Hallelujah
(Won a ri wonder)
Mo ni Badmus ona wa a la
Ti n ba n lo lona maa ko ire
Abo mi ma n da ire
Gbogbo irin ti mo ba n rin ma n d′oore
Gbogbo i e ti mo ba n se lo ma n d′ope
Ti n ba n bo ni ibikan
Ti n lo si ibikan
Maa gba ire
Ti mo ya si ibi kan ma gb'ope
Ona mi ma n fo ire
Olodumare lo je ko ri bee
E ni mo ya ma n dake s′ope
Olodumare olori
Olodumare adari
Olodumare mare
Olodumare mare
Sebi iwo ni adakeja bi idan
Bi I Ogberikusa
It's just by the way
Bi Olorun ni bee
E o le ba mi ja it′s just by His grace
I shall never fall
Iya o le je mi tori mi o p'awo da
Okanlomo (Anaconda)
Colour media
(Cosatira)
Hallelujah
(Won a ri wonder)
(Won a ri wonder)
Mo ni Badmus ona wa a la
Se mi loore a epe
Se mi loore a epe
Saanu omo o re
Se mi loore a epe
Se mi loore a epe
Saanu omo o re
Se mi loore a epe
Se mi loore a epe
Saanu omo o re
It′s Bizzle on the mix
Check Lyrics of latest songs here, and get fresh updates as they drop via X and Facebook





