Jerimoyah Lyrics by Wizka

SHARE

Wizka Lyrics

Embrace the power of words and music with the heartfelt lyrics of Wizka's Jerimoyah.

Jerimoyah Cover Art

Wizka - Jerimoyah Lyrics

Ohh oh yeah
Ehe Ehe
Wizka micro scope
Oh oh
Yeah yeah yeah
Ehe he he
Jerimoyah l'é
Rimoyah l'èmèjè
Train Wavy TK, mix it, baby
Oh, Yeah-ay-ay-ay
Jerimoyah l'é, Jerimoyah l'èmèjè
Jerimoyah l'émèjè, aw-l'émèjè

Jerimoyah le meje
Oba to n gbe de kede
Oba to n dari so mo meje
Ohh
Oba ti o ma la fi we
E je a so tan jomo meji
Lo ba lo so do wolii
Ko le do la ko le di yii
Wolii soro fun akoko
Wipe owo bo wa fun
Shogbon lala po ju
Fun omo eda Adamu

Wolii te si wa ju lo
Lo ba n soro fun ikeji
Wi pe a ro wo ojiji
To ba ko aje meji
Lowo awon jomoh meji
Wipe e wi e te fe si
Lowuro fun ojo meje
Sugbon ranti eni keji

Oba mi a ma da saara
Ko si eni imi
To ba deni o le do la
Ko do di fun keji
Oba mi a ma dara
Oju aye
O ba n gbo oun time so
O ba mope ko si alaye
O ni ibi te re po sumo
Ni keji ati ako ko

Wolii ma lo n fe de fo
Wipe ko se ni body
Ta nkan t'Oluwa wi
Akoko l'ola po ju
O s'oro s'aje po ju
Ikeji d'eri iponju
O p'oshe ju aje son

Ilahi, Oba yi
Ma shee wo mi
Abiamo t'oloja yi
Mo d'ero t'ori gahin, Ilahi

Oba mi a ma d'ara sha, rara, kos'eni bi (ye-ye)
T'oba d'eni, o le d'ola, ko d'odi fun ikeji
Oba mi a ma d'ara sha, rara, kos'eni bi
T'oba d'eni, o le d'ola, ko d'odi fun ikeji

Oba mi a ma d'ara sha, rara, kos'eni bi
O le d'ola
(Train Wavy TK, mix it, baby)
Ko d'odi fun ikeji

Check Lyrics of latest songs here, and get fresh updates as they drop via Twitter and Facebook

Related