
BisiManuel Lyrics
Aanu Ni by BisiManuel is a heartfelt gospel song that celebrates God's mercy and unmerited favor, read the lyrics below. The song teaches that many of life's blessings, breakthroughs, and open doors are not earned by human effort alone but are the result of divine grace. Through powerful testimonies and expressions of gratitude, Aanu Ni assures believers that God's mercy can change impossible situations, fulfill His promises, and elevate people beyond expectations, proving that His compassion is the reason behind every success and victory.
BisiManuel - Aanu Ni Lyrics
Chorus
Ohun t'awọn kan gbawẹ fun lo ṣe wẹrẹ
Omi ti wọn ni ko le ṣan to wa di ibu
Mo ni bo ṣe n ṣọla rẹ o, Oun lo ye
Aanu ni o, aanu ni
Verse 1
A ṣe iru emi le jọba
O wi ninu ọrọ rẹ, mo gba bẹẹ
A ṣe ireti tun wa fun'gi agelori
O bọrọ rẹ mu, mo gba bẹẹ
Omi odo to kan dẹ le pada dun
Gẹgẹ bi ọrọ rẹ, mo gba bẹẹ
Aanu ni
Aanu ni
Chorus
Ohun t'awọn kan gbawẹ fun lo ṣe wẹrẹ
Lo ṣe wẹrẹ
Omi ti wọn ni ko le ṣan to wa di ibu
Mo ni bo ṣe n ṣọla rẹ o, Oun lo ye
Aanu ni o, aanu ni
Verse 2
To ba jẹ ile mo ti wa ko le kan mi
Wọn ni no be hin turn
Ọwọ yẹn sọ wi pe k'ọn gbe fun mi
Ere asapojude ti gbogbo wọn sa dẹ fori mi
Aidẹ mọwa wu mi o ku da iṣẹ Ọlọrun duro
Ko da iṣẹ Ọlọrun duro o
I was barely whispering Your name
Didn't even know the words to say
But somehow doors just opened up for me
Like You were waiting where I'd be
And I don't understand it
Thats' the flavour of mercy
Chorus
Ohun t'awọn kan gbawẹ fun lo ṣe wẹrẹ
Lo ṣe wẹrẹ, lo ṣe wẹrẹ o
Omi ti wọn ni ko le ṣan to wa di ibu
Mo ni bo ṣe n ṣọla rẹ o, Oun lo ye
Aanu ni o, aanu ni
Check Lyrics of latest songs here, and get fresh updates as they drop via X and Facebook